Use your preferred language to learn new language
Son: Good afternoon mummy. | Ọmọdékùnrin: Ẹ káàsán ìyá mi. |
Mother: Good afternoon my child. | Ìyá: Káàsán ọmọ mi. |
Mother: How was school today? | Ìyá: Báwo ni ilé-ìwé òní? |
Son: It was fine mummy. | Ọmọdékùnrin: Dáradára ni ìyá mi. |
Son: How was your business today? | Ọmọdékùnrin: Báwo ni ọrọ̀-ajé yín ní òní? |
Mother: It was fine. | Ìyá: Dáradára ni. |
Thank you my child. | O ṣeun ọmọ mi. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023