Use your preferred language to learn new language
Daughter: Good morning father | Ọmọdébìnrin: Ẹ káàárọ̀ bàbá mi. |
Father: Good mornming my child. | Bàbá: Káàárọ̀ ọmọ mi. |
Father: Did you sleep well? | Bàbá: Ṣé dáradára ni o sùn? |
Daughter: Yes I slept well sir. | Ọmọdébìnrin: Bẹ́ẹ̀ni, dáradára ni mo sùn sà. |
Daughter: Did you sleep well too sir? | Ọmọdébìnrin: Ṣé dáradára ni ẹ̀yin náà sùn sà? |
Father: Thank you, I slept well too. | Bàbá: O ṣeun, dáradára ni èmi náà sùn. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023