Use your preferred language to learn new language
1. Greetings in Yorùbá culture depend on the people involved. | 1. Ìkíni ní àṣà Yorùbá dálé ẹni tí à ń kí tàbí ẹni tí ó ń kíni. |
2. ‘Ẹ’ is used to show respect to whoever is older. Examples: Good morning daddy. Good morning mummy. |
2. A má ń lo ‘Ẹ’ láti fi bọ̀wọ̀ fún ẹnikẹ́ni tí ó bá jù ẹni lọ. Àwọn àpẹrẹ: Ẹ káàárọ̀ bàbá mi. Ẹ káàárọ̀ ìyá mi. |
3. ‘Ẹ’ is also used when greeting two or more persons at a time. Examples: Good afternoon students. Good afternoon my friends. |
3. A tún má ń ló ‘Ẹ’ tí a bá ń kí ènìyàn méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ papọ̀ ní ẹ̀kan náà. Àwọn àpẹrẹ: Ẹ káàsán ẹ̀yin akẹ́kọ̀ọ́. Ẹ káàsán ẹ̀yin èyin òrẹ́ mi. |
4. ‘Ẹ’ is omitted when greeting your age mates and younger persons. Examples: Good evening my friend. Good evening my younger sister. |
4. A kì í lo ‘Ẹ’ tí a bá ń kí ẹlẹgbẹ́ ẹni àti ẹni tí a bá jù lọ . Àwọn àpẹrẹ: Káalẹ́ òrẹ́ mi. Káalẹ́ àbúrò mi lóbìnrin. |
5. Boys prostrate when greeting elders. |
5. Àwọn ọmọdékùnrin a máa dọ̀bálẹ̀ láti kí àgbàlagbà. |
|
6. Àwọn ọmọdébìnrin a máa kúnlẹ̀ láti kí àgbàlagbà. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023