Use your preferred language to learn new language
Ayọ̀kúnlé: Good morning. | Ayọ̀kúnlé: Káàárọ̀. |
Àyọ̀ká: Good morning. | Àyọ̀ká: Káàárọ̀. |
Ayọ̀kúnlé: What is your name? | Ayọ̀kúnlé: Kín ni orúkọ rẹ? |
Àyọ̀ká: My name is Àyọ̀ká. | Àyọ̀ká: Àyọ̀ká ni orúkọ mi. |
Àyọ̀ká: What is your name too? | Àyọ̀ká: Kín ni orúkọ ìrẹ náà? |
Ayọ̀kúnlé: My name is Ayọ̀kúnlé. | Ayọ̀kúnlé: Ayọ̀kúnlé ni orúkọ mi. |
Ayọ̀kúnlé: Today is my first day of school. | Ayọ̀kúnlé: Òní ni ọjọ́ àkọ́kọ́ mi ní ilé-ìwé. |
Àyọ̀ká: Today is my first day too. | Àyọ̀ká: Òní ni ọjọ́ àkọ́kọ́ èmi náà. |
Ayọ̀kúnlé: Are you excited? | Ayọ̀kúnlé: Ṣé ara à rẹ yá? |
Àyọ̀ká: Yes I am excited. | Àyọ̀ká: Bẹ́ẹ̀ni ara à mi yá. |
Àyọ̀ká: Are you excited too? | Ayọ̀kúnlé: Ṣé ara ìrẹ náà yá? |
Ayọ̀kúnlé: Yes I am excited too. | Àyọ̀ká: Bẹ́ẹ̀ni ara à mi yá. |
Ayọ̀kúnlé: Will you make new friends? | Ayọ̀kúnlé: Ṣé o ó ní ọ̀rẹ́ tuntun? |
Àyọ̀ká: Yes I will | Àyọ̀ká: Bẹ́ẹ̀ni n ó ní ọ̀rẹ́ tuntun. |
Àyọ̀ká: Will you be my friend? | Àyọ̀ká: Ṣé ìrẹ yí ò ṣe ọ̀rẹ́ mi? |
Ayọ̀kúnlé: Yes I will be your friend. | Ayọ̀kúnlé: Bẹ́ẹ̀ni èmi yíì ṣe ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ. |
Àyọ̀ká: Thank you. | Àyọ̀ká: O ṣeun. |
Ayọ̀kúnlé: You are welcome my new friend | Ayọ̀kúnlé: Káàbọ̀ ọ̀rẹ́ mi tuntun. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023