Use your preferred language to learn new language


Yorùbá vowels

Yorùbá vowels are of two (2) different types.   Fáwẹ́lì Yorùbá pín sí oríṣi méjì. 
Theey are oral vowels and nasal vowels.   Àwọ náà ni fáwẹ́lì àìránmúpè àti fáwẹ́lì àránmúpè. 
  1. There are seven (7) oral vowels. 
  1. Fáwẹ́lì àìránmúpè méje (7) ni ó wà. 
A a  A a
E e  Ee
Ẹ ẹ  Ẹẹ
I i  Ii
O o  Oo
Ọ ọ  Ọọ
U  u    Uu 
  1. There are five (5) nasal vowels. 
 
  1. Fáwẹ́lì àránmúpè márùn-ún (5) ni ó wà. 
AN an  AN an
ẸN ẹn  ẸN ẹn
IN in  IN in
ỌN ọn  ỌN ọn
UN un   UN un 
Singing the seven (7) oral vowels in a rhyme is one easy way to always remember them.   Ọ̀nà kan tí ó rọrùn jù láti lè má a ṣe ìrántí àwọn fáwẹ́lì àìránmúpè méjèèje (7) ni láti má a kọ wọ́n bí i orin ọmọdé. 
ba be bẹ bi bo bọ bu   ba be bẹ bi bo bọ bu 
da de dẹ di do dọ du   da de dẹ di do dọ du 
fa fe fẹ fi fo fọ fu  fa fe fẹ fi fo fọ fu 
ga ge gẹ gi go gọ gu   ga ge gẹ gi go gọ gu 

       

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023