Use your preferred language to learn new language
Daughter: Good evening father | Ọmọdébìnrin: Ẹ káalẹ́ bàbá mi. |
Father: Good evening my child. | Bàbá: Káalẹ́ ọmọ mi. |
Daughter: I am ready to go to bed sir. | Ọmọdébìnrin: Mo ti ṣe tán láti lọ sùn sà. |
Father: It is okay my child. | Bàbá: Kò burú ọmọ mi. |
Early to bed is early to rise. | Àtètè sùn ni àtètè jí. |
Daughter: Thank you father. | Ọmọdébìnrin: Ẹ ṣeun bàbá mi. |
Father: You are welcome my child. | Bàbá: Káàbọ̀ omo ọ̀ mi. |
Daughter: Good night sir. | Ọmọdébìnrin: Ó d’àárọ̀ sà. |
Father: Good night my daughter. | Bàbá: Ó d’àárọ̀ ọmọdébìnrin ǹ mi. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023